Princess Bunmi Olajubu, a former regent of Ikogosi Ekiti sang this evergreen song, Ẹ̀kọ́ dára púpọ̀ in 1987.

LYRICS OF EKO DARA PUPO


Ẹ̀kọ́ dára púpọ̀
Ẹ̀kọ́ ló l’ayé ta wà yí sẹ́
Ẹ̀kọ́ dára púpọ̀
Ẹ̀kọ́ ló l’ayé ta wà yí sẹ́
Ẹ̀kọ́ ló ń gbé’ni d’ẹni gíga
Ẹ̀kọ́ ló ń gbé’ni dé’pò ọlà
Ẹ dákun yé ẹ̀yin òbí wa
Tí ẹ bá l’ówó kẹ jọ̀ọ́ kẹ tọ́ wa
Ọmọ tí kò l’ẹ́kọ̀ọ́
Ó dá mi lójú pé yóò j’ìyà

Ọmọ tí kò l’ẹ́kọ̀ọ́
Ó dá mi lójú pé yóò j’ìyà
Iṣẹ́ burúkú ni wọ́n ń ṣe
Tí wọ́n bá ja’lè, wọ́n á tún f’ọ́lé
Ẹ dákun yé ẹ̀yin òbí wa
Tí ẹ bá l’ówó kẹ jọ̀ọ́ kẹ tọ́ wa

Bàtà mi á dún ko-ko-kà
Bàtà rẹ á dún ko-ko-kà
Bàtà wa á dún ko-ko-kà
Bí mo bá kà’wé mi
Bàtà mi á dún ko-ko-kà
Bàtà mi á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀ o
Bàtà rẹ á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀ o
Bàtà wa á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀ o
Tóò bá kà’wé rẹ

Bàtà rẹ á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀
Bísí kàwé rẹ – Bàtà rẹ á dún ko-ko-kà
Bóò bá kàwé rẹ – Bàtà rẹ á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀ o
Segun kàwé rẹ – Bàtà rẹ á dún ko-ko-kà
Bóò bá kàwé rẹ – Bàtà rẹ á wọ́ ṣẹrẹrẹ ní’lẹ̀ o

VIDEO OF EKO DARA PUPO

COPYRIGHT

Copyright © 2021 by My Woven Words: No part of this published blogpost and all of its contents may be reproduced, on another platform or webpage without a prior permission from My Woven Words except in the case of brief quotations cited to reference the source of the blogpost and all its content and certain other uses permitted by copyright law.

For permission requests, contact the admin on admin@johnsonokunade.com, or WhatsApp/Text him on +2347036065752

SHARE THIS POST:

The BEST way to support us is by providing funding to enable us continue this good work:

Bank: Guarantee Trust Bank (GTBank)
Account Name: Johnson Okunade
Naira Account: 0802091793
Dollar Account: 0802091803
Pounds Account: 0802091810
Euro Account: 0802091827

Business Email — hello@johnsonokunade.com

Sorry, cannot copy or rightclick.